Oriki lyrics- Tim Godfrey

Kaabiesi Atoperi Eledumare mi se
Kaabiesi Agba nla Atoperi Eledumare mi se
Baba mi Awimayehun
Baba mi Awilese o
Baba mi Aleselewi
Baba mi Baba nla ti ngbani
GbaniGbani l’ojo isoro
Eleti gb’ohun gbaroye
Afetilukara bi ajere
Erujeje l’eti okun pupa
Oba to tele bi eni nteni
O ta sanma bi eni taso

Gbongbo Idile Jesse ti ko lee ku lai

Eyin l’Oba to nse oun gbogbo l’odu lodu
Eyin l’Akoda
Eyin l’Aseda
Eyin l’Aweda
Eyin l’Ameda
Ogbagba tirin gbagba
Alagbada ina
Alawotele oorun
Alade gbedegbede bi eni n layin
Edumare moti mope mi wa f’eni t’ope ye fun
Moti fiyin feni tiyin se tiRe oo

Eni to n se mimo
To n je mimo
To n mu mimo
To n gbe bi mimo
To niwa mimo
Alade ogo
Tal’aba fi O we
Na You be ana
Na You be oni
Na You tu ni l’ola
Ope ye O o Baba
Edumare gbope wa

Tire ni o
Tire ni o
Mo fi sile fun O
Tire ni o
Tire ni o
Mo fi sile fun O

Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa

Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o
Tire ni o

My praise
My praise
Belongs to You
Belongs to You
My praise
My praise
Belongs to You
Belongs to You
Ese
Ese
Adupe o
Adupe o
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe
Igwe

Advertisements

Author: Naija Gospel Lyrics

All the lyrics you can get

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s